Use your preferred language to learn new language
Comparison of Yorùbá language and English language sounds systems. |
Àfiwé àwọn ìró èdè Yorùbá àti ìró èdè Gẹ̀ẹ́sì |
Yorùbá alphabet has twenty-five (25) letters. |
Létà márùndínlọ́gbọ̀n (25) ni ó wà ní inú álífábẹ́ẹ̀tì Yorùbá. |
English alphabet has 26 letters. |
Lẹ́tà mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n (26) ni ó wà ní inú álífábẹ́ẹ̀tì Gẹ̀ẹ́sì. |
Letters in Yorùbá alphabet that are not in English alphabat: |
Àwọn lẹ́tà tí ó wà ní inú álífábẹ́ẹ̀tì Yorùbá tí kò sí ní inú álífábẹ́ẹ̀tì Gẹ̀ẹ́sì: |
Ẹẹ, GBgb, Ọọ and Ṣṣ |
Ẹẹ, GBgb, Ọọ àti Ṣṣ |
Letters in English alphabat that are not in Yorùbá alphabet: Cc, Qq, Vv, Xx and Zz. |
Àwọn lẹ́tà tí ó wà ní inú álífábẹ́ẹ̀tì Gẹ̀ẹ́sì tí kò sí ní inú álífábẹ́ẹ̀tì Yorùbá: Cc, Qq, Vv, Xx àti Zz. |
Yorùbá alphabet English alphabet |
Álífábẹ́ẹ̀tì Yorùbá Álífábẹ́ẹ̀tì Gẹ̀ẹ́sì |
Aa Aa |
Aa Aa |
Bb Bb |
Bb Bb |
--- Cc |
--- Cc |
Dd Dd |
Dd Dd |
Ee Ee |
Ee Ee |
Ẹẹ --- |
Ẹẹ --- |
Ff Ff |
Ff Ff |
Gg Gg |
Gg Gg |
GBgb --- |
GBgb --- |
Hh Hh |
Hh Hh |
Ii Ii |
Ii Ii |
Jj Jj |
Jj Jj |
Kk Kk |
Kk Kk |
Ll Ll |
Ll Ll |
Mm Mm |
Mm Mm |
Nn Nn |
Nn Nn |
Oo Oo |
Oo Oo |
Ọọ --- |
Ọọ --- |
Pp Pp |
Pp Pp |
|
|
Rr Rr |
Rr Rr |
Ss Ss |
Ss Ss |
Ṣṣ --- |
Ṣṣ --- |
Tt Tt |
Tt Tt |
Uu Uu |
Uu Uu |
--- Vv |
--- Vv |
Ww Ww |
Ww Ww |
--- Xx |
--- Xx |
Yy Yy |
Yy Yy |
--- Zz |
--- Zz |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023