Use your preferred language to learn new language
Four letter words formation with examples of how they are used in simple sntences |
Ìṣẹ̀dá àwọn ọ̀rọ̀ oní lẹ́tà mẹ́rin àti àpẹrẹ bí a ṣe ń lò wọ́n ní inú gbólóhùn kéékèèké |
à d á n = àdán (bat) Black bat. |
à d á n = àdán Àdán dúdú. |
à gb ọ̀ n = àgbọ̀n (jaw) This is my jaw. |
à gb ọ̀ n = àgbọ̀n Àgbọ̀n mi rèé. |
à gb ọ n = àgbọn (coconut) Sweet coconut. |
à gb ọ n = àgbọn Àgbọn tí ó dùn. |
a k à n = akàn (crab) I ate a crab. |
a k à n = akàn Mo jẹ akàn kan. |
à m í n = àmín (amen) I said amen. |
à m í n = àmín Mo ṣe àmín. |
à p ọ́ n = àpọ́n (bachelor) I am a bachelor. |
à p ọ́ n = àpọ́n Àpọ́n ni mí. |
b à b á = bàbá (father) I like my father. |
b à b á = bàbá Mo fẹ́ràn bàbá mi. |
d ú r ó = dúró (wait/stop) Wait for me. |
d ú r ó = dúró Dúró dè mi. |
d ù r ù = dùrù (piano) I can play a piano. |
d ù r ù = dùrù Mo lè tẹ dùrù. |
ẹ̀ k a n = ẹ̀kan (once) Once in a year. |
ẹ̀ k a n = ẹ̀kan Ẹ̀kan ní inú ọdún. |
ẹ̀ b ù n = ẹ̀bùn (gift) I received a gift. |
ẹ̀ b ù n = ẹ̀bùn Mo gba ẹ̀bùn kan. |
f è r è = fèrè (whistle) Blow the whistle. |
f è r è = fèrè Fọn fèrè yẹn. |
i g u n = igun (corner) Five corners. |
i g u n = igun Igun márùn-ún. |
i k ù n = ikùn (belly) A big belly. |
i k ù n = ikùn Ikùn ńlá. |
ì t à n = ìtàn (story) I read a story book. |
ì t à n = ìtàn Mo ka ìwé ìtàn kan. |
i t a n = itan (thigh) A big thigh. |
i t a n = itan Itan ńlá. |
o k ù n = okùn (rope) A long rope. |
o k ù n = okùn Okùn gígùn. |
ò k u n = òkun (ocean) Ocean’s water. |
ò k u n = òkun Omi òkun. |
ọ d ú n = ọdún (year) One year old child. |
ọ d ú n = ọdún Ọmọ ọdún kan. |
ọ r ù n – ọrùn (neck) This is my neck. |
ọ r ù n – ọrùn Ọrùn mi rèé. |
ọ̀ s á n = ọ̀sán (afternoon) In the afternoon. |
ọ̀ s á n = ọ̀sán Ní ọ̀sán. |
ọ s à n = ọsàn (orange) I like orange. |
ọ s à n = ọsàn Mo fẹ́ràn ọsàn. |
p á p á = pápá (field) School play field. |
p á p á = pápá Pápá ìṣeré ilé-ìwé. |
s ọ̀ r ọ̀ = sọ̀rọ̀ (speak) Speak up. |
s ọ̀ r ọ̀ = sọ̀rọ̀ Sọ̀rọ̀ sókè. |
ṣ ò r o = ṣòro (difficult) This is not difficult. |
ṣ ò r o = ṣòro Eléyìí ò ṣòro. |
w ọ l é = wọlé (enter) Enter the class. |
w ọ l é = wọlé Wọlé sí kíláàsì. |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023