
Use your preferred language to learn new language
| Yorùbá vowels are of two (2) different types. | Fáwẹ́lì Yorùbá pín sí oríṣi méjì. |
| Theey are oral vowels and nasal vowels. | Àwọ náà ni fáwẹ́lì àìránmúpè àti fáwẹ́lì àránmúpè. |
|
|
| A a | A a |
| E e | Ee |
| Ẹ ẹ | Ẹẹ |
| I i | Ii |
| O o | Oo |
| Ọ ọ | Ọọ |
| U u | Uu |
|
|
| AN an | AN an |
| ẸN ẹn | ẸN ẹn |
| IN in | IN in |
| ỌN ọn | ỌN ọn |
| UN un | UN un |
| Singing the seven (7) oral vowels in a rhyme is one easy way to always remember them. | Ọ̀nà kan tí ó rọrùn jù láti lè má a ṣe ìrántí àwọn fáwẹ́lì àìránmúpè méjèèje (7) ni láti má a kọ wọ́n bí i orin ọmọdé. |
| ba be bẹ bi bo bọ bu | ba be bẹ bi bo bọ bu |
| da de dẹ di do dọ du | da de dẹ di do dọ du |
| fa fe fẹ fi fo fọ fu | fa fe fẹ fi fo fọ fu |
| ga ge gẹ gi go gọ gu | ga ge gẹ gi go gọ gu |
Mark as read
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023