Use your preferred language to learn new language


Word formation guidelines

  1. Tone marks are used all the time in Yorùbá language. 
 
  1. Gbogbo ìgbà ni a má ń lo àmì ohùn ní èdè Yorùbá. 
  1. Tone marks are used only on the vowels. 
 
  1. Orí àwọn fáwẹ̀lì nìkan ni a ti má ń lo àmì ohùn. 
  1. Three (3) different tone marks are used in Yorùbá language. 
 
  1. Àmì ohùn mẹ́ta (3) ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni à ń lò ní èdè Yorùbá. 
  1. They are: 
 
  1. Àwọn ni: 

i. The low tone (doh):

This is shown with grave accent (à è ẹ̀ ì ò ọ̀ ù). 

 

i. Ohùn ìsàlẹ̀ (dò): 

 Àfihàn ẹ̀ ni àmi ohùn tí ó pọ̀n sí òsì (à è ẹ̀ ì ò ọ̀ ù). 

ii. The mid or flat tone (re): 

This is shown with a macron (ā ē ẹ̄ ī ō ọ̄ ū). 

 

ii. Ohùn àárín (re):

 Àfihàn ẹ̀ ni àmi ohùn tí ó rékọjá ní orí lẹ́tà (ā ē ẹ̄ ī ō ọ̄ ū). 

iii. The high tone (mi): 

This is shown with acute accent (á é ẹ́ í ó ọ́ ú). 

 

 iii. Ohùn òkè (mí):

 Àfihàn ẹ̀ ni àmi ohùn tí ó pọ̀n sí ọ̀tún (á é ẹ́ í ó ọ́ ú). 

   
  1. These three tone marks are also called ‘doh’ ‘re’ ‘mi’, like we call the music tonic solfa doh, re, mi, fa, sol, la, and ti. 
 
  1. A tú ma ń pè àwọn ohùn mẹ́ta wọ̀nyí ní 'do' 're' 'mi' bí a ṣe má ń pe àwọn ohùn sílébù orin kíkọ doh, re, mi, fa, sol, la, àti ti. 
  1. The mid or flat tone (ā) is not always shown in writing. 
 
  1. A kìí ṣe àfihàn àmi ohùn àárín (ā) ní ọ̀rọ̀ kíkọ. 
  1. The low tone (à) and the high tone (á) are always shown. 
 
  1. Gbogbo ìgbà ni a má ń ṣe àfihàn ohùn ìsàlè (à) àti ohùn òkè (á). 
  1. These three (3) tone marks point us to how to pronounce words with the same spellings but different meanings. 
 
  1. Àwọn àmi ohùn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wọ̀nyí má ń ṣé ìtọ́ka sí bí a ṣé máa ń pe àwọn ọ̀rọ̀ tí a ṣe ẹ̀dá wọn bákan náà ṣùgbọ́n tí ìtumọ̀ wọn yàtọ̀ sí ara wọn. 
Examples:   Àwọn àpẹrẹ: 
Ọbẹ̀ (soup)    -  ọ̀bẹ (knife)   Ọbẹ̀  -    ọ̀bẹ 
   
Ẹyẹ (bird)     -  ẹ̀yẹ (merriment)   Ẹyẹ   -   ẹ̀yẹ 
   
Ẹwà (beauty) - ẹ̀wà (beans)   Ẹwà   -  ẹ̀wà 
    

 

Mark as read

Privacy policy Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023