Use your preferred language to learn new language
Note: | Kíyèsí: |
It is a good step to always identify tone marks before you spell words in yoruba language. | Ìgbésẹ̀ tí ó dára ni láti má a kọ́kọ́ ṣe ìdámọ̀ àwọn àmì ohùn kí a tó má a pe àwọn lẹ́tà inú ọ̀rọ̀ jáde ní ẹnu. |
The reason is because it is difficult to spell Yorùbá words with the tone marks on individual letters. | Ìdí ni wípé kò rọrùn láti má a pe àwọn lẹ́tà tí ó wà ní inú ọ̀rọ̀ jáde láti ẹnu ní ìkànkan pẹ̀lú àmì ohùn orí wọn. |
f ò = fò (to jump) | f ò = fò |
gb à = gbà (to receive) | gb à = gbà |
gb ọ́ = gbọ́ (to hear/heed) | gb ọ́ = gbọ́ |
j ó = jó (to dance/ to burn) | j ó = jó |
k í = kí (to greet) | k í = kí |
k ọ́ = kọ́ (to learn) | k ọ = kọ |
l ọ = lọ (go) | l ọ = lọ |
p ọ̀ = pọ̀ (to be plenty) | p ọ̀ = pọ̀ |
r í = rí (to see) | r í = rí |
s ọ = sọ (tell) | s ọ = sọ |
ṣ í = ṣí (open) | ṣ í = ṣí |
Note: | Kíyèsí: |
All Yorùbá words are pronounced exact+ly as the combined letters appear. | Bí àpapọ̀ àwọn létà inú ọ̀rọ̀ bá ṣe fi ara hàn ni a ṣe máa ń pè wọ́n. |
It is important to show tone marks on any letter that deserves one. | Ó ṣe pàtàkì láti má a fi àwọn àmì ohùn hàn ní orí lẹ́tà tí ó bá yẹ. |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023