Use your preferred language to learn new language


Simple greetings and responses in the classroom

Teacher: Good morning students.   Olùkọ́: Ẹ káàárọ̀ ẹ̀yìn akẹ́kọ̀ọ́. 
Students: Good morning teacher.   Àwọn akẹ́kọ̀ọ́: Ẹ káàárọ̀ olùkọ́. 
Teacher: Are you all doing good?   Olùkọ́: Ṣé àlàáfíà ni gbogbo yín wà? 
Students: Yes ma, we are all doing good.   Àwọn akẹ́kọ̀ọ́: Bẹ́ẹ̀ni mà, àlàáfíà ni a wà. 
Teacher: Fine.   Olùkọ́: Ó dára. 
Have you all done you homework?   Ṣé iṣẹ́ àmúrelé gbogbo yín ti wà ní ṣíṣe? 
Students: Yes ma.    Àwọn akẹ́kọ̀ọ́: Bẹ́ẹ̀ni mà. 
Teacher: Good.   Olùkọ́: Ó dára. 
A round of applause for yourselves.   Ẹ pa àtẹ́wọ́ fún ara yín. 

 

Mark as read

Privacy policy Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023