Use your preferred language to learn new language
Note: | Kíyèsí: |
It is a good step to always identify tone marks before you spell words in yoruba language. | Ìgbésẹ̀ tí ó dára ni láti má a kọ́kọ́ ṣe ìdámọ̀ àwọn àmì ohùn kí a tó má a pe àwọn lẹ́tà inú ọ̀rọ̀ jáde ní ẹnu. |
The reason is because it is difficult to spell Yorùbá words with the tone marks on individual letters. | Ìdí èyí ni wípé kò rọrùn láti má a pe àwọn lẹ́tà kàànkan tí ó wà ní inú ọ̀rọ̀ jáde ní ẹnu ní ìkànkan pẹ̀lú àmì ohùn orí wọn. |
a b o = abo (female) | a b o = abo |
à gb ẹ̀ = àgbẹ̀ (farmer) | à gb ẹ̀ = àgbẹ̀ |
a k ọ = akọ (male) | a k ọ = akọ |
a l ẹ́ = alẹ́ (night) | a l ẹ́ = alẹ́ |
à n á = àná (yesterday) | à n á = àná |
è m i = èmi (me) | è m i = èmi |
è s o = èso (seed/fruits) | è s o = èso |
f u n = fun (give) | f u n = fun |
gb ọ̀ n = gbọ̀n (shake) | gb ọ̀ n = gbọ̀n |
h à n = hàn (become obvious/to appear) | h à n = hàn |
ì l ú = ìlú (town/city) | ì l ú = ìlú |
ì m ọ̀ = ìmọ̀ (wisdom) | ì m ọ̀ = ìmọ̀ |
ì r ẹ = ìrẹ (you) | ì r ẹ = ìrẹ |
Note: | Kíyèsí: |
All Yorùbá words are pronounced exactly as the combined letters appear. | Bí àpapọ̀ àwọn létà inú ọ̀rọ̀ bá ṣe fi ara hàn ni a ṣe máa ń pè wọ́n. |
It is important to show tone marks on any letter that deserves one. | Ó ṣe pàtàkì láti má a fi àwọn àmì ohùn hàn ní orí lẹ́tà tí ó bá yẹ. |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023