Use your preferred language to learn new language
![]() Aa = Adé (Crown) |
![]() Aa = Ahọ́n (Tongue) |
![]() Aa = Ajá (Dog) |
Bb = Bàtà (Footwear) |
![]() Bb = Bóòlù (Ball) |
Bb = Bàbá (Father) |
![]() Dd = Dígí (Mirror) |
![]() Dd = Dùrù (Piano) |
![]() Dd = Dòdò (Fried plantain) |
![]() Ee = Erin (Elephant) |
![]() Ee = Èkúté (Rat) |
Ee = Eyín (Teeth) |
![]() Ẹẹ = Ẹja (Fish) |
Ẹẹ = Ẹkùn (Tiger) |
![]() Ẹẹ = Ẹṣin (Horse) |
Ff = Fìlà (Cap) |
![]() Ff = Fèrèsé (Window) |
Ff = Fèrè(Whistle) |
Gg = Gángan (Talking drum) |
![]() Gg = Gèlè (Headgear) |
Gg = Gẹrígẹrí (Barber) |
![]() Gbgb = Gbáàgúdá (Cassava) |
Gbgb = Gbòngbò (Root) |
Gbgb = Gbajúmọ̀ (Prominent person) |
![]() Hh = Há (To Scratch) |
Hh = Hó (To boil) |
![]() Hh = Hááhá (Corn sheath) |
Ii = Ìwé (Book) |
![]() Ii = Ife (Cup) |
Ii = Ilẹ̀kùn (Door) |
Jj = Jagunjagun (Soldier) |
Jj = Jígí (Eye glasses) |
Jj = Jà (To fight) |
Kk = Kẹ̀kẹ́ (Bicycle) |
Kk = Kìnìún (Lion) |
![]() Kk = Kọ́kọ́rọ́ (Key) |
![]() Ll = Lèkèélèkèé (Cattle egret) |
![]() Ll = Labalábá (Butterfly) |
Ll = Láwàní (Turban) |
Mm = Màálù (Cow) |
Mm = Mọlémọlé (Bricklayer) |
![]() Mm = Màrìwò ọ̀pe (Palm fronds) |
Nn = Ná (owó) (To spend money) |
Nn = Nùú (Wipe) |
Nn = Nàá (Whip) |
Oo = Owó (Money) |
Oo = Oúnjẹ (Food) |
![]() Oo = Odò (River) |
![]() Ọọ = Ọba (King) |
![]() Ọọ = Ọkọ́ (Hoe) |
![]() Ọọ = Ọ̀wọ̀ (Respect) |
Pp = Pẹ́pẹ́yẹ (Duck) |
![]() Pp = Pańpé (Hand cuff) |
Pp = Pàkúté (Trap) |
Rr = Ràkúnmí (Camel) |
Rr = Ràá (To buy) |
Rr = Ro (oko) (To cut grass) |
Ss Sálúbàtà (Flipflop) |
Ss Síléètì (Slate) |
Ss Sọ̀rọ̀ (Speak) |
Ṣṣ = Ṣíbí Spoon |
![]() Ṣṣ = Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ (Melodious shaker) |
Ṣṣ = Ṣòkòtò (Trousers) |
Tt = Tòlótòló (Turkey) |
Tt = Tàdáwà (Ink) |
Tt = Tákàdá (Paper) |
![]() Uu = Iṣu (Yam) |
Uu = Ojú (Eye) |
Uu = Ìlù (Drum) |
Ww = Wẹ̀ (To bath) |
Ww = Wàrà (Milk) |
Ww = Wúrà (Gold) |
![]() Yy = Yín (To lay) |
![]() Yy = Yẹtí (Earring) |
![]() Yy = Yànmùyánmú(Mosquito) |
Mark as read
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023