Use your preferred language to learn new language
![]() |
![]() |
Girl 1: Good morning. Girl 2: Good morning. |
Ọmọdébìnrin 1: Káàárọ̀. Ọmọdébìnrin 2: Káàárọ̀. |
Girl 1: What is your name? Girl 2: My name is Adépọ̀si. |
Ọmọdébìnrin 1: Kín ni orúkọ rẹ? Ọmọdébìnrin 2: Adépọ̀si ni orúkọ mi. |
Adépọ̀si: What is your name too? Girl 1: My name is Ọmọlẹwà. |
Adépọ̀si: Kín ni orúkọ ìrẹ náà? Ọmọdébìnrin 1: Ọmọlẹwà ni orúkọ mi. |
Adépọ̀si: How old are you? Ọmọlẹwà: I am 7 (7) years old. |
Adépọ̀si: Ọmọ ọdún mélòó ni ọ́? Ọmọlẹwà: Ọmọ ọdún méje (7) ni mí. |
Ọmọlẹwà: How old are you too? Adépọ̀si: I am six (6) years old. |
Ọmọlẹwà: Ọmọ ọdún mélòó ni ìrẹ náà? Adépọ̀si: Ọmọ ọdún mẹ́fà (6) ni mí. |
Ọmọlẹwà: It is alright. Adépọ̀si: It is alright. |
Ọmọlẹwà: Kò burú. Adépọ̀si: Kò burú. |
Ọmọlẹwà: Will you become my friend? Adépọ̀si: Yes, I will be happy. |
Ọmọlẹwà: Ṣé wà ṣe ọ̀rẹ́ mi? Adépọ̀si: Bẹ́ẹ̀ni, inú mi á dùn. |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023