Use your preferred language to learn new language
Wet season |
Ìgbà òjò |
Dry season |
gbà ẹ̀ẹ̀rùn |
Harmattan season |
Ìgbà ọyẹ́ |
Examples of using seasons of the year in simple sentences | Àwọn àpẹrẹ lílo àwọn ìgbà láàrín ọdún ní inú gbólóhùn kéékèèké |
Rain falls during wet season. | Òjò má a ń rọ̀ ní ìgbà òjò. |
The weather gets cold during wet season. | Ojú ọjọ́ má a ń tutù ní ìgbà òjò. |
The sun shines a lot during dry season. | Ọ̀pọ̀lọpọ̀ òòrùn má a ń ràn ní ìgbà òòrùn. |
There is a lot of heat during dry season. | Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ooru má a ń mú ní ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn. |
Dust fly around all the time in harmattan season. | Gbogbo ìgbà ni eruku má a ń fẹ́ ní ìgbà ọyẹ́. |
There is always dry air in harmattan season. | Gbogbo ìgbà ni afẹ́fẹ́ gbígbẹ má a ń fẹ́ ní ìgbà ọyẹ́. |
Mark as read
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023