Use your preferred language to learn new language
Television |
Amóhùnmáwòrán |
Home theatre |
Ẹ̀rọ orin |
Sofa |
Àga |
Centre table |
Tábìlì |
Standing fan |
Ẹ̀rọ abẹ̀bẹ̀ oníìdúró |
Ceiling fan |
Ẹ̀rọ abẹ̀bẹ̀ alájà |
Mirror |
Dígí |
Bed |
Ibùsùn |
Mat |
Ẹní |
Wall clock |
Agogo alágbèékọ́ |
Picture frames |
Àwọn fíréémù awòrán |
Dining table |
Tábìlì oúnjẹ |
Mark as read
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023