Use your preferred language to learn new language
Boy 1: Good morning. |
Ọmọdékùnrin 1: Káàárọ̀. |
Boy 2: Good morning. | Ọmọdékùnrin 2: Káàárọ̀. |
Boy 1: What is your name? | Ọmọdékùnrin 1: Kín ni orúkọ ìrẹ? |
Boy 2: My name is Kẹ́hìndé. | Ọmọdékùnrin 2: Kẹ́hìndé ni orúkọ mi. |
Kẹ́hìndé: What is your name too? | Kẹ́hìndé: Kín ni orúkọ ìrẹ náà? |
Boy 1: My name is Àkàní. | Ọmọdékùnrin 1: Àkàní ni orúkọ mi. |
Kẹ́hìndé: What is your father’s name? | Kẹ́hìndé: Kín ni orúkọ bàbá à rẹ? |
Àkàní: My father’s name is Àlùkò. | Àkàní: Àlùkò ni orúkọ bàbá à mi. |
Kẹ́hìndé: It is alright. | Kẹ́hìndé: Kò burú. |
Àkàní: It is alright. | Àkàní: Kò burú. |
Àkàní: Will you become my firend? | Àkàní: Ṣé wà ṣe ọ̀rẹ́ mi? |
Kẹ́hìndé: Yes, I will be glad. | Kẹ́hìndé: Bẹ́ẹ̀ni, inú mi á dùn. |
Mark as read
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023