Use your preferred language to learn new language
Dawn | Ìdájí |
Morning | Òwúrọ̀/Àárọ̀ |
Noon/ Afternoon | Ọ̀sán |
Evening/Dusk | Ìrọ̀lẹ́ |
Night | Alẹ́ |
Midnight | Agbedeméjì òru |
Earliest hours of the day (before dawn) | Òru |
Examples of how to use periods of the day in simple sentences | Àwọn àpẹrẹ lílo àkókò láàrín ọjọ́ ní inú gbólóhùn kéékèèké |
We pray at dawn. | Ìdájí ni a máa n gbàdúrà. |
Let us meet tomorrow morning. | Jẹ́ kí á pàdé ní àárọ̀ ọ̀la. |
Let us meet tomorrow at twelve noon. | Jẹ́ kí á pàdé ní agogo méjìlá ọ̀sán. |
From dusk to dawn. | Láti ìrọ̀lẹ́ títí di ìdájí. |
Moving about at night is dangerous. | Ìrìn alẹ́ ní ewu. |
I have been awake since two o’clock (2:00am). | Áti agogo méjì òru ni mo ti jí. |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023