Use your preferred language to learn new language


Days of the week

 

Sunday   Ọjọ́ Àìkú 
Monday   Ọjọ́ Ajé 
Tuesday   Ọjọ́ Ìṣẹ́gun 
Wednesday   Ọjọ́rú 
Thursday   Ọjọ́bọ̀ 
Friday   Ọjọ́ Ẹtì 
Saturday   Ọjọ́ Àbámẹ́ta 
   Orin nípa ọ̀sẹ̀.... 
Examples of using days of the week in a sentence   Àwọn àpẹrẹ lílo àwọn ọjọ́ láàrín ọ̀sẹ̀ ní inú gbólóhùn kéékèèké 
Christians go to church on Sunday.  Ọjọ́ Àìkú ni àwọn Kristiani máa ń lọ sí ilé ìjọ́sìn. 
I love to wake up to a Monday.   Mo fẹ́ràn láti máa jí sí ọjọ́ Ajé. 
My birthday falls on a Tuesday.   Ọjọ́ Ìṣẹ́gun ni ọjọ́ ìbí mi bọ́sí. 
Wednesday is mid week.   Ọjọ́rú ni agbedeméjì ọ̀sẹ̀ 
I love a Thursday too.   Mo fẹ́ràn Ọjọ́bọ̀ náà.  
Muslims pray Juma’at on Friday.   Ọjọ́ Ẹtì ni àwọn Mùsùlùmí má a ń kí Jímọ̀. 
Our meeting holds on Saturday.  Ọjọ́ Àbámẹ́ta ni ìpàdé wa. 

 

Mark as read

Privacy policy Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023