Use your preferred language to learn new language
Adébọ́lá: Good afternoon Àkànní my friend. | Adébọ́lá: Àkànní ọ̀rẹ́ mi, káàsán. |
Àkànní: Thank you Adébọ́lá my friend. | Àkànní: Ọ̀rẹ́ mi Adébọ́lá káàsán. |
Adébọ́lá: Greetings about hot weather. | Adébọ́lá: A kú ooru yìí o. |
Àkànní: We are coping my friend. | Àkànní: Ọ̀rẹ́ mi, àwa nì yẹn o. |
Àkànní: I hope the heat is not harsh on you. | Àkànní: Mo lérò pé ìmọ̀lára ooru yìí ò pọ̀jù. |
Adébọ́lá: This is too much on me my friend. | Adébọ́lá: Ọ̀rẹ́ mi, eléyìí pọ̀jù ní ara mi. |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023