Use your preferred language to learn new language


Greetings and responses during wet season between Ayọ̀kúnlé’s mum and Àyọ̀ká’s mum

 

Ayọ̀kúnlé’s mum: Hello Àyọ̀ká’s mum.   Ìya Ayọ̀kúnlé: Ẹ ǹlẹ́ o ìyá Àyọ̀ká. 
Àyọ̀ká’s mum: Hello Ayọ̀kúnlé’s mum.   Ìyá Àyọ̀ká: Ẹ ǹlẹ́ o ìya Ayọ̀kúnlé. 
Ayọ̀kúnlé’s mum: Greetings about the rain.   Ìya Ayọ̀kúnlé: Ẹ kú òjò o. 
Àyọ̀ká’s mum: We are coping.   Ìyá Àyọ̀ká: Àwa nì yẹn o. 
Ayọ̀kúnlé’s mum: I hope the rain is not affecting sales.   Ìyá Àyọ̀ká: Mo lérò pé òjò ò yọ ọrọ̀ ajé ní ẹnu. 
Àyọ̀ká’s mum: It is bearable.   Ìya Ayọ̀kúnlé: Kò kọ́ja ìfaradà o. 
Ayọ̀kúnlé’s mum: How is sales over there too?   Ìya Ayọ̀kúnlé: Ọrọ̀ ajé ti ìrẹ náà ńkọ́? 
Àyọ̀ká’s mum: Thank you, it is going on well.   Ìya Àyọ̀ká: Adúpẹ́ o, ó ń lọ dáradára. 
Mark as read

Privacy policy Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023