Use your preferred language to learn new language
Mr. Ọláwálé: Well done Mr. Akin. | Ọ̀gbẹ́ni Ọláwálé: Ẹ kú iṣẹ́ o ọ̀gbẹ́ni Akin. |
Mr. Akin: Thank you Mr. Ọláwálé. | Ọ̀gbẹ́ni Akin: Ẹ ṣeun o ọ̀gbẹ́ni Ọláwálé. |
Mr. Akin: How is work? | Ọ̀gbẹ́ni Akin: Iṣẹ́ ńkọ́? |
Mr. Ọláwálé: It is going on well, thank you. | Ọ̀gbẹ́ni Ọláwálé: Adúpẹ́, ó ń lọ dáradára. |
Mr. Ọláwálé: How is your work too? | Ọ̀gbẹ́ni Ọláwálé: Iṣẹ́ ti ẹ̀yin náà ńkọ́? |
Mr. Akin: It is also going on well, thank you. | Ọ̀gbẹ́ni Akin: Adúpẹ́, dáradára náà ló ń lọ. |
Mr. Ọláwálé: It is okay. | Ọ̀gbẹ́ni Ọláwálé: Kò burú. |
Mr. Akin: It is alright. | Ọ̀gbẹ́ni Akin: Ó dára. |
Mark as read
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023