Use your preferred language to learn new language
Words and opposite with pictures |
Ìtẹ̀síwájú lóri ọ̀rọ̀ àti ìdàkejì ọ̀rọ̀ pẹ̀lú àwòrán |
Boy Girl
Woman Man
Stand Sit
Walk Run
A tall girl A short girl
Long rope Short rope
Fat dog Thin dog
Big ball Small ball
Black White |
Ọmọdékùnrin Ọmọdébìnrin
Obìnrin Ọkùnrin
Dìde Jókòó
Rìn Sáré
Ọmọdébìnrin gíga Ọmọdébìnrin Kúkurú
Okùn Gígùn Okùn Kúkurú
Ajá Sísanra Ajá tínrín
Bọ́ọ̀lù ńlá Bọ́ọ̀lù kékeré
Dúdú Funfun |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023