Use your preferred language to learn new language
Come Come to my house. |
Wá Wá sí ilé mi. |
Go Go home. |
Lọ Lọ sí ilé. |
Enter Enter into the class. |
Wọlé Wọlé sí inú kíláàsì. |
Go out Go out of the class. |
Jáde Jáde kúrò nínú kíláàsì. |
Stand Stand to greet the teacher. |
Dìde Dìde láti kí olùkọ́. |
Stop/wait Wait for me. |
Dúró Dúró dè mí. |
Clap Clap for yourself. |
Pàtẹ́wọ́ Pàtẹ́wọ́ fún ara rẹ.. |
Speak Speak up. |
Sọ̀rọ̀ Sọ̀rọ̀ sókè. |
Write Write down these words. |
Kọ Kọ àwọn ọ̀rọ̀ yí sílẹ̀. |
Read Read this story book. |
Ka Ka ìwé ìtàn yí. |
Move Move your desk. |
Sún Sún tábìlì rẹ. |
Sleep Sleep when you get home. |
Sùn Sùn tí o bá dé ilé. |
Wake up Wake up to dress for school. |
Jí Jí láti múra ilé-ìwé. |
Carry Carry it along. |
Gbe Gbe pẹ̀lú re. |
Give Give it to Bọ́lá tomorrow. |
Fun Fi fun Bọ́lá ní ọ̀la. |
Mark as read
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023