Use your preferred language to learn new language
I am a boy. This is my head |
Ọmọdékùnrin ni mí. Orí mi rèé |
I am a girl. These is my hair. |
Ọmọdébìnrin ni mí. Irun mi rèé |
I am a girl. This is my nose. |
Ọmọdébìnrin ni mí. Imú mi rèé |
I am a boy. This is my eyebrow. |
Ọmọdékùnrin ni mí. Àwọn ìpéǹpé ojú mi rèé. |
I am a girl. This is my mouth. |
Ọmọdébìnrin ni mí. Ẹnu mi rèé |
I am boy. These are my eyes. |
Ọmọdékùnrin ni mí. Àwọn ojú mi rèé |
I am a girl. These are my teeth. |
Ọmọdébìnrin ni mí. Àwọn eyín mi rèé. |
I am a boy. This is my tongue. |
Ọmọdékùnrin ni mí. Ahọ́n mi rèé. |
I am a girl. This is my cheek. |
Ọmọdébìnrin ni mí. Ẹ̀rẹ̀kẹ́/ẹ̀kẹ́ mi rèé. |
I am a girl. This is my lip. |
Ọmọdébìnrin ni mí. Ètè mi rèé. |
I am a boy. These are my shoulders |
Ọmọdékùnrin ni mí. Àwọn èjìká mi rèé |
I am a girl. These are my ears. |
Ọọmọdébìnrin ni mí. Àwọn etí mi rèé |
I am a boy. This is my chest. |
Ọmọdékùnrin ni mí. Àyà mi rèé. |
I am a girl. This is my neck. |
Ọmọdébìnrin ni mí. Ọrùn mi rèé |
I am a boy. These are my knees. |
Ọmọdékùnrin ni mí. Orókún mi rèé. |
I am a girl. This is my waist. |
Ọmọdébìnrin ni mí. Ìbàdí mi rèé |
I am a boy. These are my legs |
Ọmọdékùnrin ni mí. Àwọn ẹsẹ̀ mi rèé. |
I am a girl. This are my eye lashes. |
Ọmọdébìnrin ni mí. Àwọn irun ojú mi rèé. |
I am boy. These are my toes. |
Ọmọdékùnrin ni mí. Àwọn ìka ẹsẹ̀ mi rèé |
Mark as read
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023