Use your preferred language to learn new language
![]() |
![]() |
Àyọ̀ká: Good afternnon Ayọ̀kúnlé my friend. | Àyọ̀ká: Ayọ̀kúnlé ọ̀rẹ́ mi, káàsán. |
Àyọ̀ká: Did today’s study go well? | Àyọ̀ká: Ṣé dáradára ni ẹ̀kọ́ òní lọ? |
Ayọ̀kúnlé: Yes, it went well, | Ayọ̀kúnlé: Bẹ́ẹ̀ni, dáradára ló lọ. |
Ayọ̀kúnlé: How about yours? | Ayọ̀kúnlé: Ẹ̀kọ́ tì ìrẹ náà ń kọ́? |
Àyọ̀ká: Thank you, mine went fine too. | Àyọ̀ká: Mo dúpẹ́, ẹ̀kọ́ mi náà lọ dáradára. |
Àyọ̀ká: Are ready to go home? | Àyọ̀ká: Ṣé o ti ṣe tán láti má a lọ sí ilé? |
Ayọ̀kúnlé: Yes, i am ready. | Ayọ̀kúnlé: Bẹ́ẹ̀ni, mo ti ṣe tán. |
Àyọ̀ká: I am ready too. | Àyọ̀ká: Èmi náà ti ṣe tán. |
Ayọ̀kúnlé: It is okay. | Ayọ̀kúnlé: Kò burú. |
Àyọ̀ká: Let us walk together. | Àyọ̀ká: Jẹ́ kí á jọ rìn papọ̀. |
Ayọ̀kúnlé: It is alright, let us go. | Ayọ̀kúnlé: Ó dára, jẹ́ kí á má a lọ. |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023