Use your preferred language to learn new language
Jew's Mallow/Jute leaves |
Ewédú |
Malabar Spinach |
Ẹ̀fọ amúnútutù |
Bitter leaves |
Ewúro |
Water leaves |
Ẹ̀fọ gbúre |
African basil (scent leaf) |
Efinrin |
African spinach |
Ẹ̀fọ ṣọkọ |
Amaranth Greens |
Ẹ̀fọ tẹ̀tẹ̀ |
Snake tomato |
Ẹ̀fọ tòmátì eléjò |
Glossy night shade leaves |
Ẹ̀fọ òdú |
African Eggplant leaves |
Ẹ̀fọ igbó |
Wild Lettuce |
Ẹ̀fọ yanrìn |
Mushroom |
Olú |
Bologi |
Ẹ̀fọ wọ̀rọ̀wọ́ |
Fire weed |
Ẹ̀fọ ebòlò |
Onion |
Àlùbọ́sà |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023