Use your preferred language to learn new language
Three letter words formation and examples of how we use them in simple sentences. |
Ìṣẹ̀dá àwọn ọ̀rọ̀ oní lẹ́tà méta àti àpẹrẹ bí a ṣe ń lò wọ́n ní inú àwọn gbólóhùn kéékèèké. |
Note: It is a good step to always identify tone marks before you spell words in yoruba language. The reason is because it is difficult to spell Yorùbá words with the tone marks on individual letters. |
Kíyèsí: Ìgbésẹ̀ tí ó dára ni láti má a kọ́kọ́ ṣe ìdámọ̀ àwọn àmì ohùn kí a tó má a pe àwọn lẹ́tà inú ọ̀rọ̀ jáde ní ẹnu. Ìdí ni wípé kò rọrùn láti má a pe àwọn lẹ́tà tí ó wà ní inú ọ̀rọ̀ jáde láti ẹnu ní ìkànkan pẹ̀lú àmì ohùn orí wọn. |
a d é = adé (crown) The king’s Crown. |
a d é = adé Adé ọba. |
a b o = abo (female) It is a female. |
a b o = abo Abo ni. |
à g é = àgé (kettle) My kettle broke. |
à g é = àgé Àgé mi fọ́. |
à gb a = àgbà (elder) Respect elders. |
à gb a = àgbà Bọ̀wọ̀ fún àgbà. |
à l ọ́ = àlọ́ (tale) Tell us a tale. |
à l ọ́ = àlọ́ Pa àlọ́ fún wa. |
ẹ y ọ = ẹyọ (piece) How much a piece? |
ẹ y ọ = ẹyọ Èló ni ẹyọ kan? |
è s o = èso (seed) I love fruits. |
è s o = èso Mo fẹ́ràn èso. |
f ú n = fun (for) Leave it for him. |
f u n = fun Fí sílẹ̀ fun. |
f u n = fún (give) Give it to me. |
f ú n = fún Fi fún mi . |
g ú n = gún (pound) Pound yam. |
g ú n = gún Gún iyán. |
gb ọ̀ n = gbọ̀n (shake) Do not shake. |
gb ọ̀ n = gbọ̀n Má Gbọ̀n. |
h à n = hàn (show) Show it to me. |
h à n = hàn Fi hàn mí. |
i b à = ibà (fever) I have a fever. |
i b à = ibà Mo ní ibà. |
i f e = ife (cup) Buy a new cup. |
i f e = ife Ra ife tuntun. |
ì l ú = ìlú (town/city) This is my city. |
ì l ú = ìlú Ìlú mi rèé. |
ì l ù = ìlù (drum) The drum is loud. |
ì l ù = ìlù Ìlù yẹn ń pariwo. |
ì m ọ̀ = ìmọ̀ (wisdom) Apply wisdom. |
ì m ọ̀ = ìmọ̀ Lo ìmọ̀. |
ò b í = òbí (parent) It is for my parent. |
ò b í = òbí Ti òbí mi ni. |
ò s ì = òsì (left) Turn left. |
ò s ì = òsì Yà sí òsì. |
s á n = sán (to crack) Crack the wall. |
s á n = sán Sán ògiri. |
s ú n = sún (move) Move your table. |
s ú n = sún Sún tábìlì rẹ. |
w ọ́ n = wọ́n (expensive) It is expensive. |
w ọ́ n = wọ́n Ó wọ́n. |
Note: All Yorùbá words are pronounced exact+ly as the combined letters appear. It is important to show tone marks on every letter that deserves one. |
Kíyèsí: Bí àpapọ̀ àwọn létà inú ọ̀rọ̀ bá ṣe fi ara hàn ni a ṣe máa ń pè wọ́n. Ó ṣe pàtàkì láti má a fi àwọn àmì ohùn hàn ní orí lẹ́tà tí ó bá yẹ. |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023