Use your preferred language to learn new language


Syllables

Syllables Sílébù
What is a syllable? Kín ni sílébù?
A syllable is a unit of sound that is produced when pronouncing a word or parts of word. Sílébù ni ègé ọ̀rọ̀ tí a lè fi ohùn gbé jáde ní ẹ̀kan ṣoṣo.
The number of tone marks that appear on a word determines the number of syllables in Yorùbá language. Ní èdè Yorùbá, iye àmì ohùn tí ó wà ní orí ọ̀rọ̀ ni ó má ń ṣe ìtọ́ka sí iye sílébù tí ó wà ní inú ọ̀rọ̀ náà.
This means that, every syllable contains at least a vowel or a vowel with one or more consonants. Èyí túnmọ̀ sí wípé gbogbo sílébù gbọdọ̀ ní fáwẹ̀lì kan ṣoṣo tàbí fáwẹ̀lì kan pẹ̀lú kọ́nsónántì kan tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ.

Types of syllable

ÀWỌN IRÚURÚ SÍLÉBÙ

1. One syllable words/Monosyllables

1. Àwọn ọ̀rọ̀ onísílébù kan

2. Two syllable words

2. Àwọn ọ̀rọ̀ onísílébù méjì

3. Three syllable words

3. Àwọn ọ̀rọ̀ onísílébù mẹ́ta

4. Four syllable words

4. Àwọn ọ̀rọ̀ onísílébù mérin

5. Multiple syllable words/Polysyllable

5. Àwọn ọ̀rọ̀ onísílébù púpọ̀

   

Examples of one (1) syllable words

Àpẹrẹ àwọn ọ̀rọ̀ onísílébù kan (1)

Fun = Fun (give) Fun = Fun
Kọ = Kọ (write) Kọ = Kọ
Lọ =Lọ (go) Lọ = Lọ
Sùn = Sùn (sleep) Sùn = Sùn
= Wá (come) = Wá
   

Examples of two (2) syllable words

Àpẹrẹ àwọn ọ̀rọ̀ onísílébù méjì (2)

À + gbẹ̀ = Àgbẹ̀ (farmer) À + gbẹ̀ = Àgbẹ̀
A + bo = Abo (female) A + bo = Abo
A + kọ = Akọ (male) A + kọ = Akọ
Ò + bí = Òbí (parent) Ò + bí = Òbí
Sọ̀ + rọ̀ = Sọ̀rọ̀ (speak) Sọ̀ + rọ̀ = Sọ̀rọ̀
Wọ + lé = Wọlé (enter) Wọ + lé = Wọlé
   

Examples of three (3) syllable words

Àpẹrẹ àwọn ọ̀rọ̀ onísílébù mẹ́ta (3)

À + pẹ + rẹ = Àpẹrẹ (example) À + pẹ + rẹ = Àpẹrẹ
À + tẹ́ + wọ́ = Àtẹ́wọ́ (applause) À + tẹ́ + wọ́ = Àtẹ́wọ́
È + nì + yàn = Ènìyàn (person) È + nì + yàn = Ènìyàn
Ì + jọ + ba = Ìjọba (government) Ì + jọ + ba = Ìjọba
Jó + kò + ó = Jókòó (to sit) Jó + kò + ó = Jókòó
   

Examples of four (4) syllable words

Àpẹrẹ àwọn ọ̀rọ̀ onísílébù mẹ́rin (4)

À + gbà + la + gbà = Àgbàlagbà (elderly) À + gbà + la + gbà = Àgbàlagbà
Ì + dá + ni + mọ̀ = Ìdánimọ̀ (identification) Ì + dá + ni + mọ̀ = Ìdánimọ̀
Ì + gbé + ra + ga = Ìgbéraga (pride) Ì + gbé + ra + ga = Ìgbéraga
Ì + ràn + lọ́ + wọ́ = Ìrànlọ́wọ́ (help) Ì + ràn + lọ́ + wọ́ = Ìrànlọ́wọ́
La + ba + lá + bá = Labalábá (butterfly) La + ba + lá + bá = Labalábá
Ọ̀ + pọ̀ + lọ + pọ̀ = Ọ̀pọ̀lọpọ̀ (several) Ọ̀ + pọ̀ + lọ + pọ̀ = Ọ̀pọ̀lọpọ̀
À + á + dọ́ + ta = Àádọ́ta (fifty) À + á + dọ́ + ta = Àádọ́ta
Ọ + gọ́ + rùn + -ún = Ọgọ́rùn-ún (hundred) Ọ + gọ́ + rùn + -ún = Ọgọ́rùn-ún
Tò + ló + tò + ló = Tòlótòló (turkey) Tò + ló + tò + ló = Tòlótòló
   

Examples of Polysyllable syllable words

Àpẹrẹ àwọn ọ̀rọ̀ onísílébù púpọ̀

A + gbó + hùn + sá + fẹ́ + fẹ́

= Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ (loud speaker)

A + gbó + hùn + sá + fẹ́ + fẹ́

= Agbóhùnsáfẹ́fẹ́

A + mó + hùn + má + wò + rán

= Amóhùnmáwòrán (television)

A + mó + hùn + má + wò + rán

= Amóhùnmáwòrán

À + tẹ́ + lẹ́ + -ọ + wọ́ = Àtẹ́lẹ́-ọwọ́ (palm) À + tẹ́ + lẹ́ + -ọ + wọ́ = Àtẹ́lẹ́-ọwọ́
Ì + fọ̀ + kàn + ba + lẹ̀ = Ìfọ̀kànbalẹ̀ (peace of mind) Ì + fọ̀ + kàn + ba + lẹ̀ = Ìfọ̀kànbalẹ̀
Ì + dà + gbà + só + kè = Ìdàgbàsókè (development/growth) Ì + dà + gbà + só + kè = Ìdàgbàsókè

O + ó + kàn + dín + lá + à + á + dọ́ + ta

= Oókàndínláàádọ́ta (forty-nine)

O + ó + kàn + dín + lá + à + á + dọ́ + ta

= Oókàndínláàádọ́ta

Mọ́ + kàn + dín + lọ́ + gọ́ + ta

= Mọ́kàndínlọ́gọ́ta (fifty-nine)

Mọ́ + kàn + dín + lọ́ + gọ́ + ta

= Mọ́kàndínlọ́gọ́ta

Mọ́ + kàn + dín + lá + à + á + dọ́ + rin

= Mọ́kàndínláàádọ́rin (sixty-nine)

Mọ́ + kàn + dín + lá + à + á + dọ́ + rin

= Mọ́kàndínláàádọ́rin

Mọ́ + kàn + dín + lọ́ + gọ́ + rin

= Mọ́kàndínlọ́gọ́rin (seventy-nine)

Mọ́ + kàn + dín + lọ́ + gọ́ + rin

= Mọ́kàndínlọ́gọ́rin

Mọ́ + kàn + dín + lá + à + á + dọ́ + rùn + -ún = Mọ́kàndínláàádọ́rùn-ún (eighty-nine) Mọ́ + kàn + dín + lá + à + á + dọ́ + rùn + -ún = Mọ́kàndínláàádọ́rùn-ún
   
Mark as read

Privacy policy Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023