Use your preferred language to learn new language
Counting amount of money | Kíka iye owó |
Note: |
Kíyèsí: |
1.It is important to understand Yorùbá numerals to be able to count amount of money in Yorùbá language. |
1. Mímọ àwọn òǹkà Yorùbá ṣe pàtàkì láti lè ka iye owó ní èdè Yorùbá. |
2.A single rule applies to counting money in Yorùbá language whether it is in Naira, Dollar, Pound, Euro, Yen, Yuan, and so on. | 2. Bó jẹ́ Náírà (₦), tàbí Dọ́là ($), tàbí Pọ́ùn (£), tàbí Yúrò (€), tàbí Yẹ́ẹ̀nì (¥), tàbí Yùáànù (CN¥) àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ, ìlànà kan ṣoṣo náà ni a ń lò láti fi ka iye àwọn owó ní èdè Yorùbá. |
Counting smallest units of money: | Kíka ẹ̀yà inú owó tí ó kéré jùlọ: |
One hundred kọ́bọ̀ makes one naira (₦1.00). | Ọgọ́rùn-ún kọ́bọ̀ jẹ́ Náírà kan (₦1.00). |
One hundred cents make one Dollar ($1). | Ọgọ́rùn-ún sẹ́ẹ̀ntì jẹ́ Dọ́là kan ($1). |
One hundred pence make one Pound (£1). | Ọgọ́rùn-ún pẹ́ẹ̀nsì jẹ́ Pọ́ùn kan (£1). |
One hundred Euro cents make one Euro (€1). | Ọgọ́rùn-ún sẹ́ẹ̀ntì Yúrò jẹ́ Yúrò kan (€). |
Counting amount of money in Nigerian Naira (₦) | Kíka iye owó ní Náírà (₦) Nàìjíríà |
Fifty kọ́bọ̀ (₦0.50k) | Àádọ́ta kọ́bọ̀ (₦0.50k) |
Ninety-nine kọ́bọ̀ (₦0.99k) | Kọ́bọ̀ mókàndínlọ́gọ́rùn-ún (₦0.99k) |
One hundred kọ́bọ̀ (₦1.00k) | Ọgọ́rùn-ún kọ́bọ̀ (₦1.00k) |
One naira (₦1.00) | Náírà kan (₦1.00) |
Two naira (₦2.00) | Náírà méjì (₦2.00) |
Three naira (₦3.00) | Náírà mẹ́ta (₦3.00) |
Four naira (₦4.00) | Náírà mẹ́rin (₦4.00) |
Five naira (₦5.00) | Náírà márùn-ún (₦5.00) |
Six naira (₦6.00) | Náírà mẹ́fà (₦6.00) |
Seven naira (₦7.00) | Náírà méje (₦7.00) |
Eight naira (₦8.00) | Náírà mẹ́jọ (₦8.00) |
Nine naira (₦9.00) | Náírà mẹ́sàn-án (₦9.00) |
Ten naira (₦10.00) | Náírà mẹ́wàá (₦10.00) |
Eleven naira (₦11.00) | Náírà mọ́kànlá (₦11.00) |
Twelve naira (₦12.00) | Náírà méjìlá (₦12.00) |
Thirteen naira (₦13.00) | Náírà mẹ́tàlá (₦13.00) |
Fourteen naira (₦14.00) | Náírà mẹ́rìnlá (₦14.00) |
Fifteen naira (₦15.00) | Náírà márùndínlógún (₦15.00) |
Sixteen naira (₦16.00) | Náírà mẹ́rìndínlógún (₦16.00) |
Seventeen naira (₦17.00) | Náírà mẹ́tàdínlógún (₦17.00) |
Eighteen naira (₦18.00) | Náírà méjìdínlógún (₦18.00) |
Nineteen naira (₦19.00) | Náírà mọ́kàndínlógún (₦19.00) |
Twenty naira (₦20.00) | Ogún náírà (₦20.00) |
Note how we write the currency before the amount of the money from one naira (₦1.00) to nineteen naira (₦19.00). | Kíyèsí bíí a ṣe ń kọ ẹ̀yà owó ṣáájú iye owó láti náírà kan (₦1.00) sí náírà mọ́kàndínlógún (₦19.00). |
As from twenty (20), amount comes before currency on every tenth number that comes after. | Iye owó má a ń ṣáájú ẹ̀yà owó láti orí ogún (20) àti gbogbo àwọn nọ́mbà ìkẹwàá tí ó tẹ̀lé. |
Twnety-one naira (₦21.00) | Náírà mọ́kànlélógún (₦21.00) |
Twnety-two naira (₦22.00) | Náírà méjìlélógún (₦22.00) |
Twnety-three naira (₦23.00) | Náírà mẹ́tàlélógún (₦23.00) |
Twnety-four naira (₦24.00) | Náírà mẹ́rìnlélógún (₦24.00) |
Twnety-five naira (₦25.00) | Náírà Márùndínlọ́gbọ̀n (₦25.00) |
Twnety-six naira (₦26.00) | Náírà Mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n (₦26.00) |
Twnety-seven naira (₦27.00) | Náírà Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n (₦27.00) |
Twnety-eight naira (₦28.00) | Náírà Méjìdínlọ́gbọ̀n (₦28.00) |
Twnety-nine naira (₦29.00) | Náírà Mọ́kàndínlọ́gbọ̀n (₦29.00) |
Thirty naira (₦30.00) | Ọgbọ̀n Náírà (₦30.00) |
Thirty-one naira (₦31.00) | Náírà Mọ́kànlélọ́gbọ̀n (₦31.00) |
Thirty-two naira (₦32.00) | Náírà Méjìlélọ́gbọ̀n (₦32.00) |
Thirty-three naira (₦33.00) | Náírà Mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (₦33.00) |
Thirty-four naira (₦34.00) | Náírà Mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n (₦34.00) |
Thirty-five naira (₦35.00) | Náírà Márùndínlógójì (₦35.00) |
Thirty-six naira (₦36.00) | Náírà Mẹ́rìndínlógójì (₦36.00) |
Thirty-seven naira (₦37.00) | Náírà Mẹ́tàdínlógójì (₦37.00) |
Thirty-eight naira (₦38.00) | Náírà Méjìdínlógójì (₦38.00) |
Thirty-nine naira (₦39.00) | Náírà Mọ́kàndínlógójì (₦39.00) |
Forty naira (₦40.00) | Ogójì Náírà (₦40.00) |
Forty-one naira (₦41.00) | Náírà Mọ́kànlélógójì (₦41.00) |
Forty-two naira (₦42.00) | Náírà Méjìlélógójì (₦42.00) |
Forty-three naira (₦43.00) | Náírà Mẹ́tàlélógójì (₦43.00) |
Forty-four naira (₦44.00) | Náírà Mẹ́rìnlélógójì (₦44.00) |
Forty-five naira (₦45.00) | Náírà Márùndínláàádọ́ta (₦45.00) |
Forty-six naira. (₦46.00) | Náírà Mẹ́rìndínláàádọ́ta (₦46.00) |
Forty-seven naira (₦47.00) | Náírà Mẹ́tàdínláàádọ́ta (₦47.00) |
Forty-eight naira (₦48.00) | Náírà Méjìdínláàádọ́ta (₦48.00) |
Forty-nine naira (₦49.00) | Náírà Mọ́kàndínláàádọ́ta (₦49.00) |
Fifty naira (₦50.00) | Àádọ́ta Náírà (₦50.00) |
Fifty-one naira (₦51.00) | Náírà Mọ́kànléláàádọ́ta (₦51.00) |
Fifty-two naira (₦52.00) | Náírà Méjìléláàádọ́ta (₦52.00) |
Fifty-three naira (₦53.00) | Náírà Mẹ́tàléláàádọ́ta (₦53.00) |
Fifty-four naira (₦54.00) | Náírà Mẹ́rìnléláàádọ́ta (₦54.00) |
Fifty-five naira (₦55.00) | Náírà Márùndínlọ́gọ́ta (₦55.00) |
Fifty-six naira (₦56.00) | Náírà Mẹ́rìndínlọ́gọ́ta (₦56.00) |
Fifty-seven naira (₦57.00) | Náírà Mẹ́tàdínlọ́gọ́ta (₦57.00) |
Fifty-eight naira (₦58.00) | Náírà Méjìdínlọ́gọ́ta (₦58.00) |
Fifty-nine naira (₦59.00) | Náírà Mọ́kàndínlọ́gọ́ta (₦59.00) |
Sixty naira (₦60.00) | Ọgọ́ta Náírà (₦60.00) |
Sixty-one naira (₦61.00) | Náírà Mọ́kànlélọ́gọ́ta (₦61.00) |
Sixty-two naira (₦62.00) | Náírà Méjìlélọ́gọ́ta (₦62.00) |
Sixty-three naira (₦63.00) | Náírà Mẹ́tàlélọ́gọ́ta (₦63.00) |
Sixty-four naira (₦64.00) | Náírà Mẹ́rìnlélọ́gọ́ta (₦64.00) |
Sixty-five naira (₦65.00) | Náírà Márùndínláàádọ́rin (₦65.00) |
Sixty-six naira (₦66.00) | Náírà Mẹ́rìndínláàádọ́rin (₦66.00) |
Sixty-seven naira (₦67.00) | Náírà Mẹ́tàdínláàádọ́rin (₦67.00) |
Sixty-eight naira (₦68.00) | Náírà Méjìdínláàádọ́rin (₦68.00) |
Sixty-nine naira (₦69.00) | Náírà Mọ́kàndínláàádọ́rin (₦69.00) |
Seventy naira (₦70.00) | Àádọ́rin Náírà (₦70.00) |
Seventy-one naira (₦71.00) | Náírà Mọ́kànléláàádọ́rin (₦71.00) |
Seventy-two naira (₦72.00) | Náírà Méjìléláàádọ́rin (₦72.00) |
Seventy-three naira (₦73.00) | Náírà Mẹ́tàléláàádọ́rin (₦73.00) |
Seventy-four naira (₦74.00) | Náírà Mẹ́rìnléláàádọ́rin (₦74.00) |
Seventy-five naira (₦75.00) | Náírà Márùndínlọ́gọ́rin (₦75.00) |
Seventy-six naira (₦76.00) | Náírà Mẹ́rìndínlọ́gọ́rin (₦76.00) |
Seventy-seven naira (₦77.00) | Náírà Mẹ́tàdínlọ́gọ́rin (₦77.00) |
Seventy-eight naira (₦78.00) | Náírà Méjìdínlọ́gọ́rin (₦78.00) |
Seventy-nine naira (₦79.00) | Náírà Mọ́kàndínlọ́gọ́rin (₦79.00) |
Eighty naira (₦80.00) | Ọgọ́rin Náírà (₦80.00) |
Eighty-one naira (₦81.00) | Náírà Mọ́kànlélọ́gọ́rin (₦81.00) |
Eighty-two naira (₦82.00) | Náírà Méjìlélọ́gọ́rin (₦82.00) |
Eighty-three naira (₦83.00) | Náírà Mẹ́tàlélọ́gọ́rin (₦83.00) |
Eighty-four naira (₦84.00) | Náírà Mẹ́rìnlélọ́gọ́rin (₦84.00) |
Eighty-five naira (₦85.00) | Náírà Márùndínláàádọ́rùn-ún (₦85.00) |
Eighty-six naira (₦86.00) | Náírà Mẹ́rìndínláàádọ́rùn-ún (₦86.00) |
Eighty-seven naira (₦87.00) | Náírà mẹ́tàdínláàádọ́rùn-ún (₦87.00) |
Eighty-eight naira (₦88.00) | Náírà méjìdínláàádọ́rùn-ún (₦88.00) |
Eighty-nine naira (₦89.00) | Náírà mọ́kàndínláàádọ́rùn-ún (₦89.00) |
Ninety naira (₦90.00) | Àádọ́rùn-ún Náírà (₦90.00) |
Ninety-one naira (₦91.00) | Náírà mọ́kànléláàádórùn-ún (₦91.00) |
Ninety-two naira (₦92.00) | Náírà méjìléláàádọ́rùn-ún (₦92.00) |
Ninety-three naira (₦93.00) | Náírà mẹ́tàléláàádọ́rùn-ún (₦93.00) |
Ninety-four naira (₦94.00) | Náírà mẹ́rìnléláàádọ́rùn-ún (₦94.00) |
Ninety-five naira (₦95.00) | Náírà márùndínlọ́gọ́rùn-ún (₦95.00) |
Ninety-six naira (₦96.00) | Náírà mẹ́rìndínlọ́gọ́rùn-ún (₦96.00) |
Ninety-seven naira (₦97.00) | Náírà mẹ́tàdínlọ́gọ́rùn-ún (₦97.00) |
Ninety-eight naira (₦98.00) | Náírà méjìdínlọ́gọ́rùn-ún (₦98.00) |
Ninety-nine naira (₦99.00) | Náírà mọ́kàndínlọ́gọ́rùn-ún (₦99.00) |
One hundred naira (₦100.00) | Ọgọ́rùn-ún Náírà (₦100.00) |
Mark as read
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023