Use your preferred language to learn new language
Simple greetings and responses between a Ayọ̀kúnlé and elder Ògúnkúnlé. | Ìkíni àti ìjẹ́ni kéékèèké láàrín Ayọ̀kúnlé àti alàgbà Ògúnkúnlé. |
Ayọ̀kúnlé: Good morning elder. Elder Ògúnkúnlé: Good morning Ayọ̀kúnlé. |
Ayọ̀kúnlé: Ẹ káàárọ̀ alàgbà. Alàgbà Ògúnkúnlé: Káàárọ̀ Ayọ̀kúnlé |
Elder Ògúnkúnlé: It has been a while. Ayọ̀kúnlé: Yes sir, it has been more than a while. |
Alàgbà Ògúnkúnlé: Kú ọjọ́ mẹ́ta. Ayọ̀kúnlé: Bẹ́ẹ̀ni sà, ó tó ọjọ́ mẹ́ta. |
Elder Ògúnkúnlé: How are your parents? Ayọ̀kúnlé: They are good sir. |
Alàgbà Ògúnkúnlé: Àwọn òbí rẹ ńkọ́? Ayọ̀kúnlé: Dáadáa ni wọ́n wà sà. |
Ayọ̀kúnlé: How are your children too sir? Elder Ògúnkúnlé: They are good too. |
Ayọ̀kúnlé: Àwọn ọmọ yín náà ńkọ́ sà? Alàgbà Ògúnkúnlé: Àlááfíà ni àwọn náà wà. |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023