Use your preferred language to learn new language
Simple greetings and responses between Àyọ̀ká and Ayọ̀kúnlé’s mum | Ìkíni àti ìjẹ́ni kéékèèké láàrín Àyọ̀ká àti ìya Ayọ̀kúnlé |
Àyọ̀ká: Good afternoon ma. Ayọ̀kúnlé’s mum: Good afternoon Àyọ̀ká. |
Àyọ̀ká: Ẹ káàsán mà Ìya Ayọ̀kúnlé: Káàsán Àyọ̀ká |
Ayọ̀kúnlé’s mum: How are your parents? Àyọ̀ká: They went for my father’s relatives’ meeting. |
Ìya Ayọ̀kúnlé: Àwọn òbí rẹ ńkọ́? Àyọ̀ká: Wọ́n lọ ìpàdé mọ̀lẹ́bí bàbá mi. |
Ayọ̀kúnlé’s mum: Say my greetings to them when they return. | Ìya Ayọ̀kúnlé: Bá mi kí wọn tí wọ́n bá dé. |
Àyọ̀ká: I will deliver your message ma. | Àyọ̀ká: Mà á jẹ́ iṣẹ́ yín mà. |
Ayọ̀kúnlé’s mum: I am also going out right now. | Ìya Ayọ̀kúnlé: Èmì náà ń jáde báyìí. |
Àyọ̀ká: It is okay ma. | Àyọ̀ká: Kò burú ma. |
Àyọ̀ká: Bye ma. Ayọ̀kúnlé’s mum: Thank you Àyọ̀ká. Bye. |
Àyọ̀ká: Ó di àbọ̀ mà. Ìya Ayọ̀kúnlé: O ṣeun Àyọ̀ká, Ó di àbọ̀. |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023