Use your preferred language to learn new language
Primary colours |
Àwọn àwọ̀ àkọ́kọ́ |
Primary colours are colours that cannot be derived through other colours. | Àwọn àwọ̀ àkọ́kọ́ ni àwọn àwọ̀ tí a kò lè ṣe ẹ̀dá wọn nípasẹ̀ pipo àwọn àwọ̀ òmíràn papọ̀. |
There are three (3) primary colours. |
Àwọn àwọ̀ àkọ́kọ́ oríṣi mẹ́ta ló wà. |
Colour red |
Àwọ̀ pupa |
Colour yellow |
Àwọ̀ ìyèyè |
Colour blue |
Àwọ̀ aró |
Mark as read
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023