Use your preferred language to learn new language


Secondary colours

Secondary colours Àwọn àwọ̀ atẹ̀lé
Secondary colours are the colours we derive by mixing two (2) primary colours together Àwọn àwọ̀ atẹ̀lé ni àwọn àwọ̀ tí a lè ṣe ẹ̀dá wọn nípasẹ̀ pipo àwọ̀ àkọ́kọ́ méjì pọ̀.
Red + Yellow = Orange

Colour orange can be derived by mixing red and yellow together.

Àwọ̀ pupa + Àwọ̀ ìyèyè = Àwọ̀ òféèfé

A lè ṣe ẹ̀dá àwọ̀ òféèfé nípasẹ̀ pipo àwọ̀ pupa àti àwọ̀ ìyèyè papọ̀.

Yellow + Blue = Green

Colour green can be derived by mixing yellow and blue together.

Àwọ̀ ìyèyè + Àwọ̀ aró = Àwọ̀ ewé

A lè ṣe ẹ̀dá àwọ̀ ewé nípasẹ̀ pipo àwọ̀ ìyèyè àti àwọ̀ aró papọ̀.

Blue + Red = Purple

Colour purple can be derived by mixing blue and red together.

Àwọ̀ aró + Àwọ̀ pupa = Àwọ̀ elése àlùkò

A lè ṣe ẹ̀dá àwọ̀ elése àlùkò nípasẹ̀ pipo àwọ̀ aró àti àwọ̀ pupa papọ̀.

 

Mark as read

Privacy policy Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023