Use your preferred language to learn new language
Names of different colours |
Orúkọ àwọn àwọ̀ oríṣiríṣi |
White |
Àwọ̀ funfun |
Black |
Àwọ̀ dúdú |
Red |
Àwọ̀ pupa |
Blue |
Àwọ̀ aró |
Sky blue |
Àwọ̀ ojú-òrun |
Yellow |
Àwọ̀ ìyèyè |
Green (colour of vegetations) |
Àwọ̀ ewé Àwọ̀ ewéko |
Orange |
Àwọ̀ òféèfé Àwọ̀ omi ọsàn |
Brown |
Àwọ̀ igi Àwọ̀ ara |
Pink |
Àwọ̀ pupa fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́ |
Purple |
Àwọ̀ elese àlùkò |
Indigo |
Àwọ̀ dúdú aró |
Ash/Grey |
Àwọ̀ eérú |
Silver |
Àwọ̀ fàdákà |
Gold |
Àwọ̀ wúrà |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023