Use your preferred language to learn new language
Vocabularies about time, day, week, month, year and weather |
Àwọn fokabúlárì tí ó ṣe pàtàkì nípa àkókò, ọjọ́, ọ̀sẹ̀, oṣù, ọdún àti ojú-ọjọ́ |
Darkness |
Òkùnkùn |
Light |
Ìmọ́lẹ̀ |
Moon |
Òṣùpá |
Star |
Ìràwọ̀ |
Sun |
Òòrùn |
Air |
Afẹ́fẹ́ |
Breeze |
Atẹ́gùn |
Moisture |
Èèrì |
Weather |
Ojú-ọjọ́ |
Sky |
Òfurufú Ojú-ọ̀run |
Cloud |
Sánmọ̀ |
Thunder |
Àrá |
Wind |
Ìjì |
Time |
Àkókò |
Seconds |
Ìṣẹ́jú-àáyá |
Minutes |
Ìṣẹ́jú |
Hour |
Wákàtí |
Day |
Ọjọ́ |
Week |
Ọ̀sẹ̀ |
Month |
Oṣù |
Year |
Ọdún |
Calendar |
Kọ́jọ́dá |
Season |
Ìgbà Àsìkò |
Decade |
Ẹ̀wádún |
Century |
Ọrúndún |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023