Use your preferred language to learn new language
Identification of places inside the house |
Dídá àwọn ibi inú ilé mọ̀ |
Bedroom Room |
Yàrá ìbùsùn Yàrá |
Chamber |
Ìyẹ̀wù |
Livingroom |
Yàrá ìgbàlejò |
Kitchen |
Ilé ìdáná |
Library |
Yàrá ìkàwé |
Bathroom |
Balùwẹ̀ |
Toilet |
Ilé ìgbọ̀nsẹ̀ Yàrá ìgbọ̀nsẹ̀ Ilé ìyàgbẹ́ Yàrá ìyàgbẹ́ |
Store |
Yàrá ìkó nǹkan sí |
Laundry room |
Yàrá ìfọṣọ |
Dinning area |
Agbègbè ìjẹun |
Entrance door |
Ilẹ̀kùn àbáwọlé |
Exit door |
Ilẹ̀kùn àbájáde |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023