Use your preferred language to learn new language
Cardinal Number |
Nọ́mbà iye |
A cardinal number is a number we use to tell of the amount of something or person. |
Nọ́mbà iye ni nọ́mbà tí a máa ń lò láti fi sọ iye nǹkan tàbí ènìyàn. |
One
One teacher; One of them. |
Kan Ìkan
Olùkọ́ kan Ìkan nínú wọn. |
Two
Two books. |
Méjì
Ìwé méjì. |
Three
Three tables. |
Mẹ́ta
Tábìlì mẹ́ta. |
Four
Four cats. |
Mẹ́rin
Ológbò mẹ́rin. |
Five
Five cars. |
Márùn-ún
Ọkọ̀ márùn-ún. |
Six
Six bags. |
Mẹ́fà
Àpò mẹ́fà. |
Seven
Seven stars. |
Méje
Ìràwọ̀ méje. |
Eight
Eight pencils. |
Mẹ́jọ
Lẹ́ẹ̀dì mẹ́jọ. |
Nine
Nine pens. |
Mẹ́sàn-án
Ohun ìkọ̀wé mẹ́sàn-án |
Ten
Ten fingers. |
Mẹ́wàá
Ìka mẹ́wàá. |
Evelen
Eleven chairs. |
Mọ́kànlá
Àga mọ́kànlá. |
Twelve
Twelve students. |
Méjìlá
Akẹ́kọ̀ọ́ méjìlá. |
Thirteen
Thirteen balls. |
Mẹ́tàlá
Bọ́ọ̀lù mẹ́tàlá. |
Fourteen
Fourteen angles. |
Mẹ́rìnlá
Igun mẹ́rìnlá. |
Fifteen
Fifteen stars. |
Márùndínlógún
Ìràwọ̀ márùndínlógún. |
Sixteen
Sixteen trees. |
Mẹ́rìndínlógún
Igi mẹ́rìndínlógún. |
Seventeen
Seventeen crabs. |
Mẹ́tàdínlógún
Akàn mẹ́tàdínlógún. |
Eighteen
Eighteen oranges. |
Méjìdínlógún
Ọsàn méjìdínlógún. |
Nineteen
Nineteen shoes. |
Mọ́kàndínlógún
Bàtà mọ́kàndínlógún. |
Twenty
Twenty flip-flop. |
Ogún
Ogún sálúbàtà. |
Twnety-one
Twnety-one pencils. |
Mọ́kànlélógún
Lẹ́ẹ̀dì mọ́kànlélógún. |
Twnety-two
Twnety-two bags. |
Méjìlélógún
Àpò méjìlélógún. |
Twnety-three
Twnety-three beds. |
Mẹ́tàlélógún
ìbùsùn mẹ́tàlélógún. |
Twnety-four
Twnety-four tables. |
Mẹ́rìnlélógún
Tábìlì mẹ́rìnlélógún. |
Twnety-five
Twnety-five shoes. |
Márùndínlọ́gbọ̀n
Bàtà márùndínlọ́gbọ̀n. |
Twnety-six
Twnety-six clocks. |
Mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n
Agogo Mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n. |
Twnety-seven
Twnety-seven dogs. |
Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n
Ajá mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n. |
Twnety-eight
Twnety-eight bats. |
Méjìdínlọ́gbọ̀n
Àdán méjìdínlọ́gbọ̀n. |
Twnety-nine
Twnety-nine eggs. |
Mọ́kàndínlọ́gbọ̀n
Ẹyin mọ́kàndínlọ́gbọ̀n. |
Thirty
Thirty books. |
Ọgbọ̀n
Ọgbọ̀n ìwé. |
Thirty-one
Thirty-one mirrors. |
Mọ́kànlélọ́gbọ̀n
Dígí mọ́kànlélọ́gbọ̀n. |
Thirty-two
Thirty-two glasses. |
Méjìlélọ́gbọ̀n
Jígí méjìlélọ́gbọ̀n. |
Thirty-three
Thirty-three cups. |
Mẹ́tàlélọ́gbọ̀n
Ife mẹ́tàlélọ́gbọ̀n. |
Thirty-four
Thirty-four plates. |
Mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n
Abọ́ mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n. |
Thirty-five
Thirty-five spoons. |
Márùndínlógójì
Ṣíbí márùndínlógójì. |
Thirty-six
Thirty-six rocks. |
Mẹ́rìndínlógójì
Àpáta mẹ́rìndínlógójì. |
Thirty-seven
Thirty-seven pillows. |
Mẹ́tàdínlógójì
Ìrọ̀rí mẹ́tàdínlógójì. |
Thirty-eight
Thirty-eight nets. |
Méjìdínlógójì
Àwọ̀n méjìdínlógójì. |
Thirty-nine
Thirty-nine doors. |
Mọ́kàndínlógójì
Ilẹ̀kùn mọ́kàndínlógójì. |
Forty
Forty windows. |
Ogójì
Ogójì fèrèsé. |
Forty-one
Forty-one days. |
Mọ́kànlélógójì
Ọjọ́ mọ́kànlélógójì. |
Forty-two
Forty-two students. |
Méjìlélógójì
Akẹ́kọ̀ọ́ méjìlélógójì. |
Forty-three
Forty-three teachers. |
Mẹ́tàlélógójì
Olùkọ́ mẹ́tàlélógójì. |
Forty-four
Forty-four kettles. |
Mẹ́rìnlélógójì
Àgé mẹ́rìnlélógójì. |
Forty-five
Forty-five mats. |
Márùndínláàádọ́ta
Ẹní márùndínláàádọ́ta. |
Forty-six
Forty-six crowns. |
Mẹ́rìndínláàádọ́ta
Adé mẹ́rìndínláàádọ́ta. |
Forty-seven
Forty-seven kings. |
Mẹ́tàdínláàádọ́ta
Ọba mẹ́tàdínláàádọ́ta. |
Forty-eight
Forty-eight trees. |
Méjìdínláàádọ́ta
Igi méjìdínláàádọ́ta. |
Forty-nine
Forty-nine towns. |
Mọ́kàndínláàádọ́ta
Ìlú mọ́kàndínláàádọ́ta. |
Fifty
Fifty names. |
Àádọ́ta
Àádọ́ta orúkọ |
Fifty-one
Fifty-one chiefs. |
Mọ́kànléláàádọ́ta
Olóyè mọ́kànléláàádọ́ta. |
Fifty-two
Fifty-two generations. |
Méjìléláàádọ́ta
Ìran méjìléláàádọ́ta. |
Fifty-three
Fifty-three months. |
Mẹ́tàléláàádọ́ta
Oṣù mẹ́tàléláàádọ́ta. |
Fifty-four
Fifty-four heads. |
Mẹ́rìnléláàádọ́ta
Orí mẹ́rìnléláàádọ́ta. |
Fifty-five
Fifty-five trees. |
Márùndínlọ́gọ́ta
Igi márùndínlọ́gọ́ta. |
Fifty-six
Fifty-six ropes. |
Mẹ́rìndínlọ́gọ́ta
Okùn mẹ́rìndínlọ́gọ́ta. |
Fifty-seven
Fifty-seven feet. |
Mẹ́tàdínlọ́gọ́ta
Ẹsẹ̀ mẹ́tàdínlọ́gọ́ta. |
Fifty-eight
Fifty-eight times. |
Méjìdínlọ́gọ́ta
Ìgbà méjìdínlọ́gọ́ta. |
Fifty-nine
Fifty-nine naira. |
Mọ́kàndínlọ́gọ́ta
Náírà mọ́kàndínlọ́gọ́ta. |
Sixty
Sixty schools. |
Ọgọ́ta
Ọgọ́ta ilé-ìwé |
Sixty-one
Sixty-one clothes. |
Mọ́kànlélọ́gọ́ta
Aṣọ mọ́kànlélọ́gọ́ta. |
Sixty-two
Sixty-two chalks. |
Méjìlélọ́gọ́ta
Ẹfun méjìlélọ́gọ́ta. |
Sixty-three
Sixty-three bags. |
Mẹ́tàlélọ́gọ́ta
Àpò mẹ́tàlélọ́gọ́ta. |
Sixty-four
Sixty-four flip-flops. |
Mẹ́rìnlélọ́gọ́ta
Sálúbàtà mẹ́rìnlélọ́gọ́ta. |
Sixty-five
Sixty-five leaves. |
Márùndínláàádọ́rin
Ewé márùndínláàádọ́rin. |
Sixty-six
Sixty-six balls. |
Mẹ́rìndínláàádọ́rin
Bọ́ọ̀lù mẹ́rìndínláàádọ́rin. |
Sixty-seven
Sixty-seven woods. |
Mẹ́tàdínláàádọ́rin
Igi mẹ́tàdínláàádọ́rin. |
Sixty-eight
Sixty-eight chairs. |
Méjìdínláàádọ́rin
Àga méjìdínláàádọ́rin. |
Sixty-nine
Sixty-nine pieces. |
Mọ́kàndínláàádọ́rin
Ẹyọ mọ́kàndínláàádọ́rin. |
Seventy
Seventy libraries. |
Àádọ́rin
Àádọ́rin ilé-ìkàwé |
Seventy-one
Seventy-one presidents. |
Mọ́kànléláàádọ́rin
Ààrẹ mọ́kànléláàádọ́rin. |
Seventy-two
Seventy-two roofs. |
Méjìléláàádọ́rin
Òrùlé méjìléláàádọ́rin. |
Seventy-three
Seventy-three groups. |
Mẹ́tàléláàádọ́rin
Ẹgbẹ́ mẹ́tàléláàádọ́rin. |
Seventy-four
Seventy-four lines. |
Mẹ́rìnléláàádọ́rin
Ilà mẹ́rìnléláàádọ́rin. |
Seventy-five
Seventy-five heads. |
Márùndínlọ́gọ́rin
Orí márùndínlọ́gọ́rin. |
Seventy-six
Seventy-six boundaries. |
Mẹ́rìndínlọ́gọ́rin
Ààlà mẹ́rìndínlọ́gọ́rin. |
Seventy-seven
Seventy-seven lawyers. |
Mẹ́tàdínlọ́gọ́rin
Agbẹjọ́rò mẹ́tàdínlọ́gọ́rin. |
Seventy-eight
Seventy-eight judges. |
Méjìdínlọ́gọ́rin
Adájọ́ méjìdínlọ́gọ́rin. |
Seventy-nine
Seventy-nine families. |
Mọ́kàndínlọ́gọ́rin
Ẹbí mọ́kàndínlọ́gọ́rin. |
Eighty
Eighty people. |
Ọgọ́rin
Ọgọ́rin ènìyàn. |
Eighty-one
Eighty-one knives. |
Mọ́kànlélọ́gọ́rin
Ọ̀bẹ mọ́kànlélọ́gọ́rin. |
Eighty-two
Eighty-two baskets. |
Méjìlélọ́gọ́rin
Apẹ̀rẹ̀ mẹ́jìlélọ́gọ́rin. |
Eighty-three
Eighty-three brothers. |
Mẹ́tàlélọ́gọ́rin
Arákùnrin mẹ́tàlélọ́gọ́rin. |
Eighty-four
Eighty-four women. |
Mẹ́rìnlélọ́gọ́rin
Arábìnrin mẹ́rìnlélọ́gọ́rin. |
Eighty-five
Eighty-five oranges. |
Márùndínláàádọ́rùn-ún
Ọsàn márùndínláàádọ́rùn-ún. |
Eighty-six
Eighty-six eggs. |
Mẹ́rìndínláàádọ́rùn-ún
Ẹyin mẹ́rìndínláàádọ́rùn-ún. |
Eighty-seven
Eighty-seven naira. |
Mẹ́tàdínláàádọ́rùn-ún
Náírà mẹ́tàdínláàádọ́rùn-ún. |
Eighty-eight
Eighty-eight times. |
Méjìdínláàádọ́rùn-ún
Ìgbà méjìdínláàádọ́rùn-ún. |
Eighty-nine
Eighty-nine fish. |
Mọ́kàndínláàádọ́rùn-ún
Ẹja mọ́kàndínláàádọ́rùn-ún. |
Ninety
Ninety governors. |
Àádọ́rùn-ún
Àádọ́rùn-ún gómìnà. |
Ninety-one
Ninety-one crabs. |
Mọ́kànléláàádọ́rùn-ún
Akàn Mọ́kànléláàádọ́rùn-ún. |
Ninety-two
Ninety-two keys. |
Méjìléláàádọ́rùn-ún
Kọ́kọ́rọ́ méjìléláàádọ́rùn-ún. |
Ninety-three
Ninety-three stars. |
Mẹ́tàléláàádọ́rùn-ún
Ìràwọ̀ mẹ́tàléláàádọ́rùn-ún. |
Ninety-four
Ninety-four doors. |
Mẹ́rìnléláàádọ́rùn-ún
Ilẹ̀kùn mẹ́rìnléláàádọ́rùn-ún. |
Ninety-five
Ninety-five snakes. |
Márùndínlọ́gọ́rùn-ún
Ejò márùndínlọ́gọ́rùn-ún. |
Ninety-six
Ninety-six monkeys. |
Mẹ́rìndínlọ́gọ́rùn-ún
Ọ̀bọ mẹ́rìndínlọ́gọ́rùn-ún. |
Ninety-seven
Ninety-seven sheep. |
Mẹ́tàdínlọ́gọ́rùn-ún
Àgùtàn mẹ́tàdínlọ́gọ́rùn-ún. |
Ninety-eight
Ninety-eight lions. |
Méjìdínlọ́gọ́rùn-ún
Kìnìún méjìdínlọ́gọ́rùn-ún. |
Ninety-nine
Ninety-nine tigers. |
Mọ́kàndínlọ́gọ́rùn-ún
Ẹkùn mọ́kàndínlọ́gọ́rùn-ún. |
One hundred
One hundred years. |
Ọgọ́rùn-ún
Ọgọ́rùn-ún ọdún. |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023