Use your preferred language to learn new language
Reading the 12-hour time with images |
Kíka àkókò wákàtí méjìlá pẹ̀lú àwòrán |
Twelve o’clock (12:00) |
Agogo méjìlá (12:00) |
One o’clock (1:00) |
Agogo kan (1:00) |
Two o’clock (2:00) |
Agogo méjì (2:00) |
Three o’clock (3:00) |
Agogo mẹ́ta (3:00) |
Four o’clock (4:00) |
Agogo mẹ́rin (4:00) |
Five o’clock (5:00) |
Agogo márùn-ún (5:00) |
Six o’clock (6:00) |
Agogo mẹ́fà (6:00) |
Seven o’clock (7:00) |
Agogo méje (7:00) |
Eight o’clock (8:00) |
Agogo méjọ (8:00) |
Nine o’clock (9:00) |
Agogo mẹ́sàn-án (9:00) |
Ten o’clock (10:00) |
Agogo mẹ́wàá (10:00) |
Eleven o’clock (11:00) |
Agogo mọ́kànlá (11:00) |
Twelve noon (12:00) |
Agogo méjìlá (12:00) |
5 minutes past twelve o’clock (12:05) |
Agogo méjìlá kọjá ìṣẹ́jú márùn-ún (12:05) |
Ten minutes past one o’clock (1:10) |
Agogo kan kọjá ìṣẹ́jú méwàá (1:10) |
Fifteen minutes past two o’clock (2:15) |
Agogo méjì kọjá ìṣẹ́jú márùndínlógún (2:15) |
Twenty minutes past three o’clock (3:20)
|
Agogo mẹ́ta kọjá ogún ìṣẹ́jú (3:20) |
Twenty-five minutes past four o’clock (4:25) |
Agogo mérin kọjá ìṣẹ́jú márùndínlọ́gbọ̀n (4:25) |
Half hour past five o’clock (5:30) |
Agogo márùn-ún àbọ̀ (5:30) Agogo márùn-ún kọjá ọgbọ̀n ìṣẹ́jú (5:30) |
Half hour past six o’clock (6:30) |
Agogo mẹ́fà àbọ̀ (6:30) Agogo mẹ́fà kọjá ọgbọ̀n ìṣẹ́jú (6:30) |
Twenty-five minutes to seven o’clock (6:35) |
Agogo méje ku ìṣẹ́jú márùndínlọ́gbọ̀n (6:35) |
Twenty minutes to eight o’clock (7:40) |
Agogo mẹ́jọ ku ogún ìṣẹ́jú (7:40) |
Fifteen minutes to nine o’clock (8:45) |
Agogo mẹ́sàn-án ku ìṣẹ́jú márùndínlógún (8:45) |
Ten minutes to ten o’clock (9:50) |
Agogo mẹ́wàá ku ìṣẹ́jú mẹ́wàá (9:50) |
Five minutes to eleven o’clock (10:55) |
Agogo mọ́kànlá ku ìṣẹ́jú márùn-ún (10:55) |
Five minutes to twelve o’clock (11:55) |
Agogo méjìlá ku ìṣẹ́jú márùn-ún (11:55) |
|
Agogo méjìlá (12:00) |
Half hour past twelve o’clock (12:30am) |
Agogo méjìlá àbọ̀ (12:30) Agogo méjìlá kọjá ọgbọ̀n ìṣẹ́jú (12:30) |
Privacy policy
•
Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023