Use your preferred language to learn new language


Reading the 24-hour time with images

Reading the 24-hour time with images

Kíka àkókò wákàtí mẹ́rìnlélógún pẹ̀lú àwòrán

00:00 hours

Agogo oódo-oódo (00:00)

01:00 hours

Agogo kan (01:00)

02:00 hours

Agogo méjì (02:00)

03:00 hours

Agogo mẹ́ta (03:00)

04:00 hours

Agogo mẹ́rin (04:00)

05:00 hours

Agogo márùn-ún (05:00)

06:00 hours

Agogo mẹ́fà (06:00)

07:00 hours

Agogo méje (07:00)

08:00 hours

Agogo méjọ (08:00)

09:00 hours

Agogo mẹ́sàn-án (09:00)

10:00 hours

Agogo mẹ́wàá (10:00)

11:00 hour

Agogo mọ́kànlá (11:00)

12:00 hours

Agogo méjìlá (12:00)

12:05 hours

Agogo méjìlá ọ̀sán kọjá ìṣẹ́jú márùn-ún (12:05)

13:00 hours

Agogo mẹ́tàlá (13:00)

13:10 hours

Agogo mẹ́tàlá kọjá ìṣẹ́jú mẹ́wàá (13:10)

14:00 hours

Agogo mẹ́rìnlá (14:00)

14:15 hours

Agogo mẹ́rìnlá kọjá ìṣẹ́jú márùndínlógún (14:15)

15:00 hours

Agogo márùndínlógún (15:00)

15:20 hours

Agogo márùndínlógún kọjá ogún ìṣẹ́jú (15:20)

16:00 hours

Agogo mẹ́rìndínlógún (16:00)

16:25 hours

Agogo mẹ́rìndínlógún kọjá ìṣẹ́jú márùndínlọ́gbọ̀n (16:25)

17:00 hours

Agogo mẹ́tàdínlógún (17:00)

17:30 hours

Agogo mẹ́tàdínlógún àbọ̀ (17:30)

 

Agogo mẹ́tàdínlógún kọjá ọgbọ̀n ìṣẹ́jú (17:30)

18:00 hours

Agogo méjìdínlógún (18:00)

18:35 hours

Agogo mọ́kàndínlógún ku ìṣẹ́jú márùndínlọ́gbọ̀n (18:35)

19:00 hours

Agogo mọ́kàndínlógún (19:00)

19:40 hours

Ogún agogo ku ogún ìṣẹ́jú (19:40)

20:00 hours

Ogún agogo (20:00)

20:45 hours

Agogo mọ́kànlélógún ku ìṣẹ́jú márùndínlógún (20:45)

21:00 hours

Agogo mọ́kànlélógún (21:00)

21:50hours

Agogo méjìlélógún ku ìṣẹ́jú mẹ́wàá (21:50)

22:00hours

Agogo méjìlélógún (22:00)

22:55hours

Agogo mẹ́tàlélógún ku ìṣẹ́jú márùn-ún (22:55)

23:00hours

Agogo mẹ́tàlélógún  (23:00)

23:55hours

Agogo mẹ́rìnlélógún ku ìṣẹ́jú márùn-ún  (23:55)

24:00 hours

00:00 hours

Agogo mẹ́rìnlélógún (24:00)

Agogo oódo-oódo (00:00)

Mark as read

Privacy policy Terms of service
Contact us
Alteerlingual © 2023